Angelique Kidjo Follow

Ominira lyrics

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aseyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji
Mmm ewa ka lo

Ka lo fè wa tchitchè kori ominira
N'tori ominira toro ishè gan
Edahoun gbogbo yin foun ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji

Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji

Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo a

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Correct these lyrics

Comments on Ominira

Submit your thoughts

These comments are owned by whoever posted them. This lyrics site is not responsible for them in any way.

© to the lyrics most likely owned by either the publisher () or
the artist(s) (Angelique Kidjo) which produced the music or artwork. Details



All Artists A-Z

Elsewhere



© might belong to the performers or owners of the songs. Lyrics may be used for private study, scholarship or academic research only.
In accordance to the Digital Millenium Copyright Act, publishers may ask to have specific lyrics removed.
This is a non-commercial site. We are not selling anything. Details
Lyricszoo content, design, layout © 2024 Lyricszoo.